2 Kíróníkà 30:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síbẹ̀ òmíràn nínú àwọn ènìyàn Áṣérì àti Mánásè àti Sébúlúnì rẹ̀ ara wọn sílẹ̀, wọ́n sì wá sí Jérúsálẹ́mù.

2 Kíróníkà 30

2 Kíróníkà 30:6-17