2 Kíróníkà 29:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Heṣekáyà sì yọ̀, àti gbogbo ènìyàn pé, Ọlọ́run ti múra àwọn ènìyàn náà sílẹ̀, nítorí lójijì ni a ṣe nǹkan náà.

2 Kíróníkà 29

2 Kíróníkà 29:33-36