2 Kíróníkà 29:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pẹ̀lú, àwọn ẹbọ sísun pàpọ̀jù, pẹ̀lú ọ̀rá ẹbọ àlàáfíà, pẹ̀lú ẹbọ ohun-mímu fún ẹbọ sísun.Bẹ́ẹ̀ ni a sì tún dá ti iṣẹ́-ìsìn ilé Olúwa sílẹ̀.

2 Kíróníkà 29

2 Kíróníkà 29:26-36