2 Kíróníkà 24:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóásì jẹ́ ọmọ ọdún méje nígbà tí ó jẹ ọba, ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ogójì ọdún. Orúkọ ìya rẹ̀ ni Ṣíbíà ti Béríṣébà.

2 Kíróníkà 24

2 Kíróníkà 24:1-5