2 Kíróníkà 21:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Baba wọn ti fún wọn ní ẹ̀bun púpọ̀ ti fàdákà àti wúrà àti àwọn ohun èlò iyebíye pẹ̀lú àwọn ìlú ààbò ní Júdà, Ṣùgbọ́n, ó ti gbé ìjọba fún Jéhóramù nítori òun ni àkọ́bí ọmọkùnrin.

2 Kíróníkà 21

2 Kíróníkà 21:1-7