2 Kíróníkà 21:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ará kùnrin Jéhóramù ọmọ Jéhóṣáfatì jẹ́ Áṣáríyà, Jèhíeli, Ṣekárià. Ásáríyàhù, Míkáélí àti Ṣefátíá. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Jéhóṣafátì ọba Ìsírẹlì.

2 Kíróníkà 21

2 Kíróníkà 21:1-6