2 Kíróníkà 21:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhórámù jẹ́ ẹni ọdún méjìlélọ́gbọ̀n (32) ní ìgbà tí ó di ọba, Ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mẹ́jọ. Ó kọjá lọ, kò sí ẹni tí ó kábàámọ̀. A sì sin ín si ìlú ńlá ti Dáfídì. Ṣùgbọ́n kì í ṣe nínú ibojì àwọn ọba.

2 Kíróníkà 21

2 Kíróníkà 21:14-20