2 Kíróníkà 21:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò kan ní ìparí ọdún kejì, àwọn ìfun rẹ̀ jáde nítorí àrùn náà ó sì kú nínu ìrora ńlá. Àwọn Ènìyàn rẹ̀ kò dá iná láti fi bọlá fún un, gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣe fún àwọn baba a rẹ̀.

2 Kíróníkà 21

2 Kíróníkà 21:12-20