2 Kíróníkà 21:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun pẹ̀lú ti kọ́ àwọn ibi gíga lórí àwọn òkè Júdà. Ó sì ti fà á kí àwọn ènìyàn Jérúsálẹ́mù ó se àgbérè pẹ̀lú ara wọn. Ó sì ti jẹ́ kí wọn ó ṣáko lọ.

2 Kíróníkà 21

2 Kíróníkà 21:8-19