2 Kíróníkà 21:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Títí di ọjọ́ òní ni Édómù ti wà ní ìṣọ̀tẹ̀ sí Júdà.Líbínà ṣọ̀tẹ̀ ní àkọ́kọ́ náà, nítorí tí Jéhórámì ti kọ Olúwa sílẹ̀, Ọlọ́run àwọn baba a rẹ̀.

2 Kíróníkà 21

2 Kíróníkà 21:5-17