2 Kíróníkà 19:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsin yìí jẹ́kí ìbẹ̀rù Olúwa kí ó wá sí orí rẹ̀. Ṣe ìdájọ́ pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́, nítorí pẹ̀lú Olúwa Ọlọ́run kò sí àìṣedéédéé tàbí ojúsàájú tàbí gbígba àbẹ̀tẹ́lẹ̀.”

2 Kíróníkà 19

2 Kíróníkà 19:1-11