2 Kíróníkà 18:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìn yìí ọba Síríà ti pàsẹ fún àwọn olórí kẹ̀kẹ́ tí ó wà ní ọ̀dọ̀ rẹ̀ pé, “Ẹ má ṣe jà pẹ̀lú ẹnìkankan, èwe tàbí àgbà àyàfi ọba Ísírẹ́lì.”

2 Kíróníkà 18

2 Kíróníkà 18:26-34