2 Kíróníkà 18:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Ísírẹ́lì sọ fún Jéhóṣáfátì pé, “Èmi yóò lọ sí ojú ìjà, ṣùgbọ́n ìwọ wọ aṣọ ìgunwà rẹ.” Bẹ́ẹ̀ ni ọba Ísírẹ́lì pa aṣọ rẹ̀ dà, ó sì lọ sí ojú ìjà.

2 Kíróníkà 18

2 Kíróníkà 18:22-34