2 Kíróníkà 17:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ̀nyí ni àwọn ọkùnrin tí ń dúró níwáju ọba, ní àyíká àwọn ẹni tí ó fi sínú ìlú olódi ní àyíká gbogbo Júdà.

2 Kíróníkà 17

2 Kíróníkà 17:15-19