2 Kíróníkà 17:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lára àwọn ará Fílístínì, mú ẹ̀bùn fàdákà gẹ́gẹ́ bí owó ọba wá fún Jéhóṣáfátì, àwọn ará Árábíà sì mú ọ̀wọ́ ẹran wá fún-un, ẹgbàrin ó dín ọ̀dúnrún àgbò àti ẹgbarìndín ní ọ̀ọ́dúnrún òbúkọ.

2 Kíróníkà 17

2 Kíróníkà 17:9-17