2 Kíróníkà 17:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbẹ̀rù Olúwa bà lórí gbogbo ìjọba ilẹ̀ tí ó yí Júdà ká, débi pé wọn kò bá Jéhóṣáfátì jagun.

2 Kíróníkà 17

2 Kíróníkà 17:9-18