2 Kíróníkà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì dá Ọlọ́run lóhùn pé, “Ìwọ ti fi àánú ńlá han Dáfídì baba à mi ìwọ sì ti fi mí jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

2 Kíróníkà 1

2 Kíróníkà 1:2-17