2 Kíróníkà 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òru ọjọ́ náà, Ọlọ́run farahàn Sólómónì, ó sì wí fún un pé, “Béèrè fún ohunkóhun tí ìwọ bá fẹ́ kí n fún ọ.”

2 Kíróníkà 1

2 Kíróníkà 1:3-8