1 Tímótíù 6:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ọ̀rọ̀ àyípo àwọn ènìyàn ọlọ́kàn èérí ti kò sí òtítọ́ nínú wọn, ti wọn ṣèbí ọ̀nà sí èrè ni ìwà-bí-Ọlọ́run; yẹra lọ́dọ̀ irú àwọn wọ̀nyí.

1 Tímótíù 6

1 Tímótíù 6:1-6