1 Tímótíù 6:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbéraga, kò mọ̀ nǹkankan, bí kò ṣe ìyànjú àti ìjà nípa ọ̀rọ̀ èyí tí ó ń mú ìlara, ìjà, ọ̀rọ̀-búburú wá,

1 Tímótíù 6

1 Tímótíù 6:1-8