1 Tímótíù 6:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnìkan ṣoṣo tí ó ní àìkú, tí ń gbé inú ìmọ́lẹ̀ tí a kò lè súnmọ́, ẹni tí ènìyàn kan kò rí rí tí a kò sì lè rí: ẹni tí ọlá àti agbára títí láé ń ṣe tirẹ̀ (Àmín).

1 Tímótíù 6

1 Tímótíù 6:13-21