1 Tímótíù 6:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ti yóò fi hàn ní ìgbà tirẹ̀, Ẹni tí í ṣe Olùbùkún àti Alágbára kan ṣoṣo náà, Ọba àwọn ọba, àti Olúwa àwọn Olúwa.

1 Tímótíù 6

1 Tímótíù 6:12-17