1 Tímótíù 6:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo paṣẹ fún ọ níwájú Ọlọ́run, tí ń sọ ohun gbogbo di ààyè, àti níwájú Jésù Kírísítì, ẹni tí ó jẹ́rìí níwájú Pọ́ńtíù Pílátù,

1 Tímótíù 6

1 Tímótíù 6:5-21