1 Tímótíù 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má a ja ìjà rere ti ìgbàgbọ́, di ìyè àìnípẹ̀kun mú nínú èyí tí a pè ọ sí, ti ìwọ sì ṣe ìjẹ́wọ́ rere níwájú ẹlẹ́rìí púpọ̀.

1 Tímótíù 6

1 Tímótíù 6:6-21