1 Tímótíù 5:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo pàṣẹ fún ọ níwájú Ọlọ́run, àti Kírísítì Jésù, àti àwọn ańgẹ́lì àyànfẹ́ kí ìwọ máa ṣakíyèsí nǹkan wọ̀nyí, láìṣe ojúṣàájú, láti fi ègbè ṣe ohunkóhun.

1 Tímótíù 5

1 Tímótíù 5:20-22