1 Tímótíù 5:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bá àwọn tí ó ṣẹ̀ wí níwájú gbogbo ènìyàn, kí àwọn ìyókù pẹ̀lú bà á lè bẹ̀rù.

1 Tímótíù 5

1 Tímótíù 5:14-25