1 Tẹsalóníkà 5:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí Ọlọ́run àlàáfíà pàápàá wẹ̀ yín mọ́, kí ó sì yà yín sọ́tọ̀ fún ara rẹ̀. Kí Ọlọ́run pa ẹ̀mí àti ọkàn pẹ̀lú ara yín mọ́, títí di ìgbà wíwá Jésù Kírísítì Olúwa wa.

1 Tẹsalóníkà 5

1 Tẹsalóníkà 5:14-28