1 Tẹsalóníkà 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìparí, ará, a sọ fún un yín bí ẹ ti ń gbé láti wu Ọlọ́run, àní gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin tí ń ṣe. Nísinsìnyìí, a bèèrè, a sì ń rọ̀ yín nínú Jésù Olúwa láti ṣe bẹ́ẹ̀ àti bẹ́ẹ̀ sí.

1 Tẹsalóníkà 4

1 Tẹsalóníkà 4:1-11