1 Tẹsalóníkà 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Nípa èyí, ọkàn yín yóò di alágbára, àìlẹ́sẹ̀ àti Mímọ́ nípa Ọlọ́run, Baba wa. Nígbà náà, ẹ ó ní ìgboyà láti dúró níwájú rẹ̀ láìṣẹ̀, ní ọjọ́ tí Olúwa wa Jésù Kírísítì yóò padà wá pẹ̀lú àwọn tí ó jẹ́ tirẹ̀.