1 Tẹsalóníkà 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò ṣé é ṣe fún wa láti dá ọpẹ́ tán lọ́wọ́ Ọlọ́run nítorí ayọ̀ àti ìfẹ́ tí ó máa ń kún ọkàn wa nípa àdúrà wa fún un yín.

1 Tẹsalóníkà 3

1 Tẹsalóníkà 3:1-13