1 Tẹsalóníkà 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí nǹkan tí a kò lè fi ara dà níwọ̀n ìgbà tí a ti mọ̀ pé, ẹ̀yin sì dúró gbọn-ingbọn-in fún Olúwa.

1 Tẹsalóníkà 3

1 Tẹsalóníkà 3:2-13