1 Sámúẹ́lì 8:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Sámúẹ́lì gbọ́ gbogbo ohun tí àwọn ènìyàn sọ, ó tún tún un sọ níwájú Olúwa.

1 Sámúẹ́lì 8

1 Sámúẹ́lì 8:20-22