1 Sámúẹ́lì 8:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Orúkọ àkọ́bí rẹ̀ a máa jẹ́ Jóẹ́lì àti orúkọ ẹ̀kejì a máa jẹ́ Ábíjà, wọ́n ṣe ìdájọ́ ní Bíáṣébà.

1 Sámúẹ́lì 8

1 Sámúẹ́lì 8:1-4