1 Sámúẹ́lì 8:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ọjọ́ náà bá dé, ẹyin yóò kígbe fún ìrànlọ́wọ́ láti ọ̀dọ̀ ọba tí ẹ̀yin ti yàn. Olúwa kò sì ní dá a yín lóhùn ní ọjọ́ náà.”

1 Sámúẹ́lì 8

1 Sámúẹ́lì 8:10-22