1 Sámúẹ́lì 8:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì mú ìdámẹ́wàá nínú àwọn agbo ẹran yín, yóò sì máa se ẹrú u rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 8

1 Sámúẹ́lì 8:12-21