1 Sámúẹ́lì 26:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì wò ó, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀mí rẹ ti tóbi lónìí lójú mi, bẹ́ẹ̀ ni ki ẹ̀mí mi ó tóbi lójú Olúwa, kí ó sì gbà mí lọ́wọ́ ibi gbogbo.”

1 Sámúẹ́lì 26

1 Sámúẹ́lì 26:22-25