1 Sámúẹ́lì 26:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí Olúwa o san án fún olúkúlùkù bí òdodo rẹ̀ àti bí òtítọ́ rẹ̀: nítorí pé Olúwa tí fi ọ lé mi lọ́wọ́ lónìí, ṣùgbọ́n èmi kò fẹ́ nawọ́ mi sí ẹni àmì òróró Olúwa.

1 Sámúẹ́lì 26

1 Sámúẹ́lì 26:22-25