1 Sámúẹ́lì 26:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù sì mọ ohùn Dáfídì, ó sì wí pé, “Ohùn rẹ ni èyí bí Dáfídì ọmọ mi?”Dáfídì sì wí pé, “Ohùn mi ni, Olúwa mi, ọba.”

1 Sámúẹ́lì 26

1 Sámúẹ́lì 26:9-18