1 Sámúẹ́lì 26:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nǹkan tí ìwọ ṣe yìí kò dára. Bí Olúwa ti ń bẹ, o tọ́ kí ẹ̀yin ó kú, nítorí pé ẹ̀yin kò pa olúwa yín mọ́, ẹni àmì òróró Olúwa. Ǹjẹ́ sì wo ibi tí ọ̀kọ̀ ọba gbé wà, àti ìgò omi tí ó ti wà ní bi tìmùtìmù rẹ̀.”

1 Sámúẹ́lì 26

1 Sámúẹ́lì 26:14-22