1 Sámúẹ́lì 25:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wólẹ̀ lẹ́bàá ẹṣẹ̀ rẹ̀, ó wí pé, “Olúwa mi, fi ẹ̀ṣẹ̀ yìí yá mi: kí ó sì jẹ́ kí ìránṣẹ́bìnrin rẹ, èmi bẹ̀ ọ́, sọ̀rọ̀ létí rẹ, kí ó sì gbọ́ ọ̀rọ̀ ìránṣẹ́bìnrin rẹ.

1 Sámúẹ́lì 25

1 Sámúẹ́lì 25:22-27