1 Sámúẹ́lì 25:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábígáílì sì rí Dáfídì, ó sì yára, ó sọ̀kalẹ̀ lórí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ó sì dojúbolẹ̀ níwájú Dáfídì, ó sì rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 25

1 Sámúẹ́lì 25:16-27