1 Sámúẹ́lì 22:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gádì wòlíì sí wí fún Dáfídì pé, “Ma ṣe gbé inú ihò náà, yẹra, kí o sí lọ sí ilẹ̀ Júdà.” Nígbà náà ni Dáfídì sì yẹra, ó sì lọ sínú igbó Hárétì.

1 Sámúẹ́lì 22

1 Sámúẹ́lì 22:1-10