1 Sámúẹ́lì 22:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì mú wọn wá ṣíwájú ọba Móábù; wọ́n sì bá á gbé ní gbogbo ọjọ́ tí Dáfídì fí wà nínú ihò náà.

1 Sámúẹ́lì 22

1 Sámúẹ́lì 22:3-14