1 Sámúẹ́lì 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ó yọ̀ fún òunjẹ ti fi ara wọn ṣe alágbàṣe,àwọn tí ebi ń pa kò sì ṣe aláìní: tóbẹ́ẹ̀ ti àgàn fi bí méje.Ẹni tí ó bímọ púpọ̀ sì di aláìlágbára.

1 Sámúẹ́lì 2

1 Sámúẹ́lì 2:1-13