1 Sámúẹ́lì 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Élì sì di arúgbó gidigidi, ó sì gbọ́ gbogbo èyí ti àwọn ọmọ rẹ̀ ṣe sí gbogbo Ísírẹ́lì; àti bi wọ́n ti máa ń bá àwọn obìnrin sùn, tí wọ́n máa ń péjọ ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ àjọ.

1 Sámúẹ́lì 2

1 Sámúẹ́lì 2:18-27