1 Sámúẹ́lì 19:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù fetísí Jónátanì, ó sì búra báyìí, “Níwọ̀n ìgbà tí Olúwa bá ti ń bẹ láàyè, a kì yóò pa Dáfídì.”

1 Sámúẹ́lì 19

1 Sámúẹ́lì 19:1-9