1 Sámúẹ́lì 19:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi ẹ̀mí rẹ̀ wéwu nígbà tí ó pa Fílístínì. Olúwa ṣẹ́ ogun ńlá fún gbogbo Ísírẹ́lì, ìwọ rí i inú rẹ dùn. Èéṣe nígbà náà tí ìwọ yóò fi ṣe ohun búburú sí ọkùnrin aláìṣẹ̀ láìnídìí?”

1 Sámúẹ́lì 19

1 Sámúẹ́lì 19:1-13