1 Sámúẹ́lì 14:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Ṣọ́ọ̀lù sì ń bá àlùfáà sọ̀rọ̀, ariwo ní ibùdó àwọn Fílístínì sì ń pọ̀ ṣíwájú sí. Ṣọ́ọ̀lù sì wí fún àlùfáà pé, “Dá ọwọ́ rẹ dúró.”

1 Sámúẹ́lì 14

1 Sámúẹ́lì 14:9-21