1 Sámúẹ́lì 14:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù sì wí fún Áhíjà pé, “Gbé àpótí Ọlọ́run wá.” Àpótí Ọlọ́run wà pẹ̀lú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ìgbà náà.

1 Sámúẹ́lì 14

1 Sámúẹ́lì 14:11-27