1 Sámúẹ́lì 13:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A kò sì rí alágbẹ̀dẹ kan ní gbogbo ilẹ̀ Ísírẹ́lì, nítorí tí àwọn Fílístínì wí pé, “Bí kò ṣe bẹ́ẹ̀ àwọn Hébérù yóò rọ idà tàbí ọ̀kọ̀!”

1 Sámúẹ́lì 13

1 Sámúẹ́lì 13:9-23